1 Kíróníkà 16:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Ẹ sọ pé, ‘Gbà wá, ìwọ Ọlọ́run ìgbàlà wa,+Kó wa jọ, kí o sì gbà wá lọ́wọ́ àwọn orílẹ̀-èdè,Ká lè máa fi ọpẹ́ fún orúkọ mímọ́ rẹ+Ká sì máa yọ̀ bí a ṣe ń yìn ọ́.*+
35 Ẹ sọ pé, ‘Gbà wá, ìwọ Ọlọ́run ìgbàlà wa,+Kó wa jọ, kí o sì gbà wá lọ́wọ́ àwọn orílẹ̀-èdè,Ká lè máa fi ọpẹ́ fún orúkọ mímọ́ rẹ+Ká sì máa yọ̀ bí a ṣe ń yìn ọ́.*+