2 Sámúẹ́lì 12:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: ‘Wò ó, màá mú kí àjálù bá ọ láti inú ilé ara rẹ;+ ojú rẹ ni màá ti gba àwọn ìyàwó rẹ,+ tí màá fi wọ́n fún ọkùnrin míì,* tí á sì bá wọn sùn ní ọ̀sán gangan.*+
11 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: ‘Wò ó, màá mú kí àjálù bá ọ láti inú ilé ara rẹ;+ ojú rẹ ni màá ti gba àwọn ìyàwó rẹ,+ tí màá fi wọ́n fún ọkùnrin míì,* tí á sì bá wọn sùn ní ọ̀sán gangan.*+