ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 35:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Àwọn tí Jèhófà rà pa dà máa pa dà wá,+ wọ́n sì máa kígbe ayọ̀ wá sí Síónì.+

      Ayọ̀ tí kò lópin máa dé orí wọn ládé.+

      Wọ́n á máa yọ̀ gidigidi, inú wọn á sì máa dùn,

      Ẹ̀dùn ọkàn àti ìbànújẹ́ kò ní sí mọ́.+

  • Jeremáyà 15:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 “Màá sì gbà ọ́ sílẹ̀ lọ́wọ́ àwọn ẹni burúkú

      Màá rà ọ́ pa dà kúrò lọ́wọ́ àwọn aláìláàánú.”

  • Míkà 4:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Máa yí nínú ìrora, ọmọbìnrin Síónì, kí o sì kérora,

      Bí obìnrin tó ń rọbí,

      Torí o máa kúrò ní ìlú, wàá sì lọ gbé ní pápá.

      O máa lọ jìnnà dé Bábílónì,+

      Ibẹ̀ ni wàá ti rí ìdáǹdè;+

      Ibẹ̀ ni Jèhófà yóò ti rà ọ́ pa dà lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá rẹ.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́