Sáàmù 34:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Bó tilẹ̀ jẹ́ pé ebi máa ń pa àwọn ọmọ kìnnìún* tó lágbára,Àmọ́ ní ti àwọn tó ń wá Jèhófà, wọn kò ní ṣaláìní ohun rere.+ Àìsáyà 55:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Kí ló dé tí ẹ fi ń sanwó fún ohun tí kì í ṣe oúnjẹ,Kí ló sì dé tí ẹ fi ń lo ohun tí ẹ ṣiṣẹ́ fún* sórí ohun tí kì í tẹ́ni lọ́rùn? Ẹ tẹ́tí sí mi dáadáa, kí ẹ sì jẹ ohun tó dáa,+Ohun tó dọ́ṣọ̀* sì máa mú inú yín dùn* gidigidi.+ Lúùkù 1:53 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 53 ó ti fi àwọn ohun rere tẹ́ àwọn tí ebi ń pa lọ́rùn dé ẹ̀kúnrẹ́rẹ́,+ ó sì ti mú kí àwọn tó lọ́rọ̀ lọ lọ́wọ́ òfo.
10 Bó tilẹ̀ jẹ́ pé ebi máa ń pa àwọn ọmọ kìnnìún* tó lágbára,Àmọ́ ní ti àwọn tó ń wá Jèhófà, wọn kò ní ṣaláìní ohun rere.+
2 Kí ló dé tí ẹ fi ń sanwó fún ohun tí kì í ṣe oúnjẹ,Kí ló sì dé tí ẹ fi ń lo ohun tí ẹ ṣiṣẹ́ fún* sórí ohun tí kì í tẹ́ni lọ́rùn? Ẹ tẹ́tí sí mi dáadáa, kí ẹ sì jẹ ohun tó dáa,+Ohun tó dọ́ṣọ̀* sì máa mú inú yín dùn* gidigidi.+
53 ó ti fi àwọn ohun rere tẹ́ àwọn tí ebi ń pa lọ́rùn dé ẹ̀kúnrẹ́rẹ́,+ ó sì ti mú kí àwọn tó lọ́rọ̀ lọ lọ́wọ́ òfo.