-
Jónà 1:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Lẹ́yìn náà, Jèhófà mú kí ìjì kan tó lágbára jà lórí òkun, ìjì náà sì le débi pé ọkọ̀ náà fẹ́rẹ̀ẹ́ ya.
-
-
Jónà 1:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Àmọ́ àwọn ọkùnrin náà fi gbogbo okun wọn tukọ̀ náà* kí wọ́n lè ṣẹ́rí rẹ̀ pa dà sí etíkun, ṣùgbọ́n wọn ò rí i ṣe, torí ìjì náà ń le sí i níbi tí wọ́n wà.
-