-
Jónà 1:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Ni wọ́n bá ké pe Jèhófà, wọ́n sì sọ pé: “Jèhófà, jọ̀ọ́, má ṣe jẹ́ ká ṣègbé nítorí ọkùnrin yìí!* Jèhófà, jọ̀ọ́ má ka ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ sí wa lọ́rùn, torí o ti ṣe ohun tí o fẹ́.”
-