ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Àwọn Ọba 3:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 nítorí ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Ẹ kò ní rí ìjì, bẹ́ẹ̀ ni ẹ kò ní rí òjò; síbẹ̀, omi máa kún àfonífojì yìí,+ ẹ ó sì mu látinú rẹ̀, ẹ̀yin àti àwọn ẹran ọ̀sìn yín pẹ̀lú àwọn ẹran míì tí ẹ ní.”’

  • Àìsáyà 35:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  7 Ilẹ̀ tí ooru ti mú kó gbẹ táútáú máa di adágún omi tí esùsú* kún inú rẹ̀,

      Ilẹ̀ gbígbẹ sì máa di ìsun omi.+

      Koríko tútù, esùsú àti òrépèté

      Máa wà ní ibùgbé tí àwọn ajáko* ti ń sinmi.+

  • Àìsáyà 41:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Màá mú kí odò ṣàn lórí àwọn òkè tí nǹkan ò hù sí,+

      Màá sì mú kí omi sun ní àwọn pẹ̀tẹ́lẹ̀.+

      Màá sọ aginjù di adágún omi tí esùsú* kún inú rẹ̀,

      Màá sì sọ ilẹ̀ tí kò lómi di orísun omi.  +

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́