Sáàmù 107:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ó mú wọn gba ọ̀nà tí ó tọ́+Kí wọ́n lè dé ìlú tí wọ́n á lè máa gbé.+