Àìsáyà 65:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Wọ́n á kọ́ ilé, wọ́n sì máa gbé inú wọn,+Wọ́n á gbin ọgbà àjàrà, wọ́n sì máa jẹ èso wọn.+