ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 64:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  9 Nígbà náà, ẹ̀rù á ba gbogbo èèyàn,

      Wọ́n á máa kéde ohun tí Ọlọ́run ti ṣe,

      Wọ́n á sì lóye àwọn iṣẹ́ rẹ̀ jinlẹ̀.+

  • Hósíà 14:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  9 Ta ni ó gbọ́n? Kí ó lóye nǹkan wọ̀nyí.

      Ta ni ó lóye? Kí ó mọ̀ wọ́n.

      Nítorí àwọn ọ̀nà Jèhófà tọ́,+

      Àwọn olódodo yóò sì máa rìn nínú wọn;

      Àmọ́, àwọn tó ń dẹ́ṣẹ̀ yóò kọsẹ̀ nínú wọn.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́