Jóṣúà 17:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ààlà Mánásè bẹ̀rẹ̀ láti Áṣérì dé Míkímẹ́tátì,+ tó dojú kọ Ṣékémù,+ ààlà náà sì lọ sí apá gúúsù,* dé ilẹ̀ àwọn tó ń gbé ní Ẹ́ń-Tápúà.
7 Ààlà Mánásè bẹ̀rẹ̀ láti Áṣérì dé Míkímẹ́tátì,+ tó dojú kọ Ṣékémù,+ ààlà náà sì lọ sí apá gúúsù,* dé ilẹ̀ àwọn tó ń gbé ní Ẹ́ń-Tápúà.