-
2 Sámúẹ́lì 3:28, 29Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
28 Nígbà tí Dáfídì wá gbọ́ nípa rẹ̀, ó ní: “Ọrùn èmi àti ìjọba mi mọ́ kúrò nínú ẹ̀bi ẹ̀jẹ̀+ Ábínérì ọmọ Nérì níwájú Jèhófà títí láé. 29 Kí ó yí dà sórí Jóábù+ àti gbogbo ilé bàbá rẹ̀. Kí ọkùnrin tí nǹkan ń dà lára rẹ̀+ tàbí tí ó jẹ́ adẹ́tẹ̀ + tàbí tí ó yarọ* tàbí ẹni tí idà pa tàbí ẹni tí kò ní oúnjẹ+ má sì tán nílé Jóábù!”
-