Jémíìsì 2:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Torí ẹni tí kì í ṣàánú kò ní rí àánú gbà nígbà ìdájọ́.+ Àánú máa ń borí ìdájọ́.