Sáàmù 31:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Gbogbo àwọn ọ̀tá mi ń fi mí ṣẹ̀sín,+Pàápàá àwọn aládùúgbò mi. Mo ti di ẹni àríbẹ̀rù lójú àwọn ojúlùmọ̀ mi;Tí wọ́n bá rí mi lóde, ṣe ni wọ́n ń sá fún mi.+
11 Gbogbo àwọn ọ̀tá mi ń fi mí ṣẹ̀sín,+Pàápàá àwọn aládùúgbò mi. Mo ti di ẹni àríbẹ̀rù lójú àwọn ojúlùmọ̀ mi;Tí wọ́n bá rí mi lóde, ṣe ni wọ́n ń sá fún mi.+