-
Sáàmù 35:26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
26 Kí ojú ti gbogbo wọn, kí wọ́n sì tẹ́,
Àwọn tó ń yọ̀ nítorí àjálù mi.
Kí àwọn tó ń gbé ara wọn ga sí mi gbé ìtìjú àti ẹ̀tẹ́ wọ̀ bí aṣọ.
-