Sáàmù 89:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Mi ò ní da májẹ̀mú mi,+Mi ò sì ní yí ohun tí ẹnu mi ti sọ pa dà.+ Sáàmù 105:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ó ń rántí májẹ̀mú rẹ̀ títí láé,+Ìlérí tó ṣe* títí dé ẹgbẹ̀rún ìran,+