Sáàmù 89:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ọlọ́run yẹ lẹ́ni tí à ń bẹ̀rù nínú ìgbìmọ̀* àwọn ẹni mímọ́;+Ó jẹ́ atóbilọ́lá àti ẹni tí ẹ̀rù rẹ̀ ń bani lójú gbogbo àwọn tó yí i ká.+ Àìsáyà 6:2, 3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Àwọn séráfù dúró lókè rẹ̀; ọ̀kọ̀ọ̀kan ní ìyẹ́ mẹ́fà. Ọ̀kọ̀ọ̀kan* fi méjì bo ojú, ó fi méjì bo ẹsẹ̀, ọ̀kọ̀ọ̀kan sì ń fi méjì fò kiri. 3 Ọ̀kan sì ń sọ fún èkejì pé: “Mímọ́, mímọ́, mímọ́ ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun.+ Ògo rẹ̀ kún gbogbo ayé.” Lúùkù 1:49 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 49 torí pé Ẹni tó lágbára ti ṣe àwọn ohun ńláńlá fún mi, mímọ́ sì ni orúkọ rẹ̀+ Ìfihàn 4:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ní ti àwọn ẹ̀dá alààyè mẹ́rin náà, ọ̀kọ̀ọ̀kan ní ìyẹ́ mẹ́fà tí ojú kún ara rẹ̀ yí ká àti lábẹ́.+ Tọ̀sántòru ni wọ́n ń sọ pé: “Mímọ́, mímọ́, mímọ́ ni Jèhófà*+ Ọlọ́run, Olódùmarè, tó ti wà tipẹ́, tó wà báyìí, tó sì ń bọ̀.”+
7 Ọlọ́run yẹ lẹ́ni tí à ń bẹ̀rù nínú ìgbìmọ̀* àwọn ẹni mímọ́;+Ó jẹ́ atóbilọ́lá àti ẹni tí ẹ̀rù rẹ̀ ń bani lójú gbogbo àwọn tó yí i ká.+
2 Àwọn séráfù dúró lókè rẹ̀; ọ̀kọ̀ọ̀kan ní ìyẹ́ mẹ́fà. Ọ̀kọ̀ọ̀kan* fi méjì bo ojú, ó fi méjì bo ẹsẹ̀, ọ̀kọ̀ọ̀kan sì ń fi méjì fò kiri. 3 Ọ̀kan sì ń sọ fún èkejì pé: “Mímọ́, mímọ́, mímọ́ ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun.+ Ògo rẹ̀ kún gbogbo ayé.”
8 Ní ti àwọn ẹ̀dá alààyè mẹ́rin náà, ọ̀kọ̀ọ̀kan ní ìyẹ́ mẹ́fà tí ojú kún ara rẹ̀ yí ká àti lábẹ́.+ Tọ̀sántòru ni wọ́n ń sọ pé: “Mímọ́, mímọ́, mímọ́ ni Jèhófà*+ Ọlọ́run, Olódùmarè, tó ti wà tipẹ́, tó wà báyìí, tó sì ń bọ̀.”+