1 Sámúẹ́lì 2:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Jèhófà ń sọni di aláìní, ó sì ń sọni di ọlọ́rọ̀;+Ó ń rẹni wálẹ̀, ó sì ń gbéni ga.+