ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Sámúẹ́lì 2:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  5 Àwọn tó ń jẹ àjẹyó á fi ara wọn ṣe alágbàṣe nítorí oúnjẹ,

      Àmọ́ ebi ò ní pa àwọn tí ebi ń pa mọ́.+

      Ẹni tó ya àgàn ti bímọ méje,+

      Àmọ́ ẹni tó ní ọmọ púpọ̀ ti wá di aláìlọ́mọ.*

  • Àìsáyà 54:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 54 “Kígbe ayọ̀, ìwọ àgàn tí kò bímọ!+

      Tújú ká, kí o sì kígbe ayọ̀,+ ìwọ tí o kò ní ìrora ìbímọ rí,+

      Torí àwọn ọmọ* ẹni tó ti di ahoro pọ̀

      Ju àwọn ọmọ obìnrin tó ní ọkọ,”*+ ni Jèhófà wí.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́