Jóṣúà 3:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 omi tó ń ṣàn wá látòkè dáwọ́ dúró. Ó dúró bí ìsédò* síbi tó jìnnà gan-an ní Ádámù, ìlú tó wà nítòsí Sárétánì, èyí tó sì lọ sí Òkun Árábà, Òkun Iyọ̀,* ṣàn lọ títí tó fi gbẹ. Omi odò náà dáwọ́ dúró, àwọn èèyàn náà sì sọdá síbi tó dojú kọ Jẹ́ríkò.
16 omi tó ń ṣàn wá látòkè dáwọ́ dúró. Ó dúró bí ìsédò* síbi tó jìnnà gan-an ní Ádámù, ìlú tó wà nítòsí Sárétánì, èyí tó sì lọ sí Òkun Árábà, Òkun Iyọ̀,* ṣàn lọ títí tó fi gbẹ. Omi odò náà dáwọ́ dúró, àwọn èèyàn náà sì sọdá síbi tó dojú kọ Jẹ́ríkò.