Àìsáyà 30:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Wò ó! Orúkọ Jèhófà ń bọ̀ láti ọ̀nà jíjìn,Inú ń bí i gan-an, ó sì ń bọ̀ pẹ̀lú àwọsánmà* tó ṣú bolẹ̀. Ìbínú kún ètè rẹ̀,Ahọ́n rẹ̀ sì dà bí iná tó ń jẹni run.+
27 Wò ó! Orúkọ Jèhófà ń bọ̀ láti ọ̀nà jíjìn,Inú ń bí i gan-an, ó sì ń bọ̀ pẹ̀lú àwọsánmà* tó ṣú bolẹ̀. Ìbínú kún ètè rẹ̀,Ahọ́n rẹ̀ sì dà bí iná tó ń jẹni run.+