-
Jóṣúà 4:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 nígbà tí Jèhófà Ọlọ́run yín mú kí omi Jọ́dánì gbẹ níwájú wọn títí wọ́n fi sọdá, bí Jèhófà Ọlọ́run yín ṣe ṣe sí Òkun Pupa nígbà tó mú kó gbẹ níwájú wa títí a fi sọdá.+
-