Àìsáyà 48:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Nítorí tèmi, àní nítorí tèmi, màá gbé ìgbésẹ̀,+Ṣé màá wá jẹ́ kí wọ́n kẹ́gàn mi ni?+ Èmi kì í fi ògo mi fún ẹlòmíì.* Jòhánù 12:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Baba, ṣe orúkọ rẹ lógo.” Ni ohùn kan+ bá dún láti ọ̀run pé: “Mo ti ṣe é lógo, màá sì tún ṣe é lógo.”+
11 Nítorí tèmi, àní nítorí tèmi, màá gbé ìgbésẹ̀,+Ṣé màá wá jẹ́ kí wọ́n kẹ́gàn mi ni?+ Èmi kì í fi ògo mi fún ẹlòmíì.*
28 Baba, ṣe orúkọ rẹ lógo.” Ni ohùn kan+ bá dún láti ọ̀run pé: “Mo ti ṣe é lógo, màá sì tún ṣe é lógo.”+