Sáàmù 138:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Màá forí balẹ̀ ní ìdojúkọ tẹ́ńpìlì mímọ́ rẹ,*+Màá sì yin orúkọ rẹ,+Nítorí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ àti òtítọ́ rẹ. Torí o ti gbé ọ̀rọ̀ rẹ àti orúkọ rẹ ga ju gbogbo nǹkan míì lọ.*
2 Màá forí balẹ̀ ní ìdojúkọ tẹ́ńpìlì mímọ́ rẹ,*+Màá sì yin orúkọ rẹ,+Nítorí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ àti òtítọ́ rẹ. Torí o ti gbé ọ̀rọ̀ rẹ àti orúkọ rẹ ga ju gbogbo nǹkan míì lọ.*