Òwe 16:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ẹni tó ń lo ìjìnlẹ̀ òye nínú ọ̀ràn yóò ṣàṣeyọrí,*Aláyọ̀ sì ni ẹni tó gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà.