Jẹ́nẹ́sísì 12:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Màá mú kí o di orílẹ̀-èdè ńlá, màá sì bù kún ọ. Màá mú kí orúkọ rẹ di ńlá, ó sì máa jẹ́ ìbùkún.+