2 Sámúẹ́lì 22:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ó tẹ ọ̀run wálẹ̀ bí ó ṣe ń sọ̀ kalẹ̀,+Ìṣúdùdù tó kàmàmà sì wà lábẹ́ ẹsẹ̀ rẹ̀.+