Sáàmù 34:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Aláìní yìí pe Jèhófà, ó sì gbọ́. Ó gbà á nínú gbogbo wàhálà rẹ̀.+ Róòmù 10:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Nítorí “gbogbo ẹni tó bá ń ké pe orúkọ Jèhófà* yóò rí ìgbàlà.”+