Róòmù 3:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ká má ri! Àmọ́ kí Ọlọ́run jẹ́ olóòótọ́,+ kódà bí gbogbo èèyàn bá tiẹ̀ jẹ́ òpùrọ́,+ bó ṣe wà lákọsílẹ̀ pé: “Kí àwọn ọ̀rọ̀ rẹ lè fi ọ́ hàn ní olódodo, kí o sì lè jàre ẹjọ́ rẹ.”+
4 Ká má ri! Àmọ́ kí Ọlọ́run jẹ́ olóòótọ́,+ kódà bí gbogbo èèyàn bá tiẹ̀ jẹ́ òpùrọ́,+ bó ṣe wà lákọsílẹ̀ pé: “Kí àwọn ọ̀rọ̀ rẹ lè fi ọ́ hàn ní olódodo, kí o sì lè jàre ẹjọ́ rẹ.”+