Sáàmù 96:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ẹ fún Jèhófà ní ògo tí ó yẹ orúkọ rẹ̀;+Ẹ mú ẹ̀bùn dání wá sínú àwọn àgbàlá rẹ̀.