Sáàmù 24:3, 4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ta ló lè gun orí òkè Jèhófà,+Ta ló sì lè dúró ní ibi mímọ́ rẹ̀? 4 Ẹni tí ọwọ́ rẹ̀ mọ́, tí ọkàn rẹ̀ sì mọ́,+Ẹni tí kò fi ẹ̀mí Mi* búra èké,Tí kò sì búra ẹ̀tàn.+
3 Ta ló lè gun orí òkè Jèhófà,+Ta ló sì lè dúró ní ibi mímọ́ rẹ̀? 4 Ẹni tí ọwọ́ rẹ̀ mọ́, tí ọkàn rẹ̀ sì mọ́,+Ẹni tí kò fi ẹ̀mí Mi* búra èké,Tí kò sì búra ẹ̀tàn.+