Àìsáyà 38:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 “Mo bẹ̀ ọ́, Jèhófà, jọ̀ọ́ rántí+ bí mo ṣe fi òtítọ́ àti gbogbo ọkàn mi rìn níwájú rẹ,+ ohun tó dáa ní ojú rẹ sì ni mo ṣe.” Hẹsikáyà sì bẹ̀rẹ̀ sí í sunkún pẹ̀rẹ̀pẹ̀rẹ̀.
3 “Mo bẹ̀ ọ́, Jèhófà, jọ̀ọ́ rántí+ bí mo ṣe fi òtítọ́ àti gbogbo ọkàn mi rìn níwájú rẹ,+ ohun tó dáa ní ojú rẹ sì ni mo ṣe.” Hẹsikáyà sì bẹ̀rẹ̀ sí í sunkún pẹ̀rẹ̀pẹ̀rẹ̀.