33 Gbogbo ọ̀nà tí Jèhófà Ọlọ́run yín pa láṣẹ fún yín ni kí ẹ máa rìn,+ kí ẹ lè máa wà láàyè, kí nǹkan lè máa lọ dáadáa fún yín, kí ẹ sì lè pẹ́ lórí ilẹ̀ tí ẹ máa gbà.+
23 Ṣùgbọ́n, mo pàṣẹ fún wọn pé: “Ẹ gbọ́ràn sí mi lẹ́nu, màá sì di Ọlọ́run yín, ẹ ó sì di èèyàn mi.+ Kí ẹ máa rìn ní ọ̀nà tí mo pa láṣẹ fún yín, kí nǹkan lè máa lọ dáadáa fún yín.”’+