-
Sáàmù 25:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Mú kí n máa rìn nínú òtítọ́ rẹ, kí o sì kọ́ mi,+
Nítorí ìwọ ni Ọlọ́run ìgbàlà mi.
ו [Wọ́ọ̀]
Ìwọ ni mo gbẹ́kẹ̀ lé láti àárọ̀ ṣúlẹ̀.
-