-
Jémíìsì 1:23-25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Torí tí ẹnikẹ́ni bá ń gbọ́ ọ̀rọ̀ náà, àmọ́ tí kò ṣe é,+ ẹni yìí dà bí èèyàn tó ń wo ojú ara rẹ̀* nínú dígí. 24 Torí ó wo ara rẹ̀, ó lọ, ó sì gbàgbé irú ẹni tí òun jẹ́ lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀. 25 Àmọ́ ẹni tó bá ń fara balẹ̀ wo inú òfin pípé+ tó jẹ́ ti òmìnira, tí kò sì yéé wò ó, kì í ṣe olùgbọ́ tó ń gbàgbé, àmọ́ ó ti di olùṣe iṣẹ́ náà; ohun tó ń ṣe á sì máa múnú rẹ̀ dùn.+
-