Sáàmù 145:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Wọ́n á máa sọ nípa ọlá ńlá ológo iyì rẹ,+Màá sì máa ṣe àṣàrò lórí àwọn iṣẹ́ àgbàyanu rẹ.