Sáàmù 119:76 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 76 Jọ̀wọ́, jẹ́ kí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀+ tù mí nínú,Gẹ́gẹ́ bí ìlérí tí o ṣe* fún ìránṣẹ́ rẹ.