Sáàmù 118:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Mo ké pe Jáà* nínú wàhálà mi;Jáà dá mi lóhùn, ó sì mú mi wá síbi ààbò.*+