Sáàmù 94:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Nígbà tí àníyàn* bò mí mọ́lẹ̀,*O tù mí nínú, o sì tù mí lára.*+ Róòmù 15:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Nítorí gbogbo ohun tí a kọ ní ìṣáájú ni a kọ fún wa láti gba ẹ̀kọ́,+ kí a lè ní ìrètí+ nípasẹ̀ ìfaradà+ wa àti nípasẹ̀ ìtùnú látinú Ìwé Mímọ́.
4 Nítorí gbogbo ohun tí a kọ ní ìṣáájú ni a kọ fún wa láti gba ẹ̀kọ́,+ kí a lè ní ìrètí+ nípasẹ̀ ìfaradà+ wa àti nípasẹ̀ ìtùnú látinú Ìwé Mímọ́.