-
Sáàmù 119:158Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
158 Ojú burúkú ni mo fi ń wo àwọn oníbékebèke,
Torí wọn kì í pa ọ̀rọ̀ rẹ mọ́.+
-
-
Òwe 28:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Àwọn tó ń pa òfin tì máa ń yin àwọn ẹni burúkú,
Àmọ́ àwọn tó ń pa òfin mọ́ máa ń bínú sí wọn.+
-