Ẹ́kísódù 19:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Lẹ́yìn náà, gbogbo àwọn èèyàn náà fohùn ṣọ̀kan, wọ́n fèsì pé: “Gbogbo ohun tí Jèhófà sọ la múra tán láti ṣe.”+ Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, Mósè mú èsì àwọn èèyàn náà tọ Jèhófà lọ.
8 Lẹ́yìn náà, gbogbo àwọn èèyàn náà fohùn ṣọ̀kan, wọ́n fèsì pé: “Gbogbo ohun tí Jèhófà sọ la múra tán láti ṣe.”+ Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, Mósè mú èsì àwọn èèyàn náà tọ Jèhófà lọ.