-
Sáàmù 119:101Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
101 Mi ò rìn ní ọ̀nà ibi èyíkéyìí,+
Kí n lè máa pa ọ̀rọ̀ rẹ mọ́.
-
-
Éfésù 5:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Nítorí náà, ẹ máa ṣọ́ra lójú méjèèjì pé bí ẹ ṣe ń rìn kì í ṣe bí aláìlọ́gbọ́n àmọ́ bí ọlọ́gbọ́n,
-