Sáàmù 40:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Láti ṣe ìfẹ́ rẹ, Ọlọ́run mi, ni inú mi dùn sí,*+Òfin rẹ sì wà nínú mi lọ́hùn-ún.+ Róòmù 7:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Nínú mi lọ́hùn-ún,+ mo nífẹ̀ẹ́ òfin Ọlọ́run gan-an,