Sáàmù 50:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ẹni tó mú ọpẹ́ wá, tí ó fi rúbọ sí mi ń yìn mí lógo,+Ní ti ẹni tó sì ń rin ọ̀nà tí ó tọ́,Màá mú kí ó rí ìgbàlà látọ̀dọ̀ mi.”+ Hósíà 14:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ẹ pa dà sọ́dọ̀ Jèhófà pẹ̀lú ọ̀rọ̀ wọ̀nyí,Ẹ sọ fún un pé, ‘Jọ̀wọ́ dárí ẹ̀ṣẹ̀ wa jì wá,+ kí o sì gba ohun rere tí a mú wá,A ó sì fi ètè wa rú ẹbọ ìyìn sí ọ+ bí ẹni fi akọ ọmọ màlúù rúbọ.* Hébérù 13:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ẹ jẹ́ ká máa rú ẹbọ ìyìn sí Ọlọ́run nípasẹ̀ rẹ̀ nígbà gbogbo,+ ìyẹn èso ètè wa+ tó ń kéde orúkọ rẹ̀ ní gbangba.+
23 Ẹni tó mú ọpẹ́ wá, tí ó fi rúbọ sí mi ń yìn mí lógo,+Ní ti ẹni tó sì ń rin ọ̀nà tí ó tọ́,Màá mú kí ó rí ìgbàlà látọ̀dọ̀ mi.”+
2 Ẹ pa dà sọ́dọ̀ Jèhófà pẹ̀lú ọ̀rọ̀ wọ̀nyí,Ẹ sọ fún un pé, ‘Jọ̀wọ́ dárí ẹ̀ṣẹ̀ wa jì wá,+ kí o sì gba ohun rere tí a mú wá,A ó sì fi ètè wa rú ẹbọ ìyìn sí ọ+ bí ẹni fi akọ ọmọ màlúù rúbọ.*
15 Ẹ jẹ́ ká máa rú ẹbọ ìyìn sí Ọlọ́run nípasẹ̀ rẹ̀ nígbà gbogbo,+ ìyẹn èso ètè wa+ tó ń kéde orúkọ rẹ̀ ní gbangba.+