ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Sámúẹ́lì 24:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Bàbá mi, wò ó, etí aṣọ àwọ̀lékè rẹ tí kò lápá rèé lọ́wọ́ mi; nígbà tí mo gé etí aṣọ àwọ̀lékè rẹ tí kò lápá, mi ò pa ọ́. Ṣé ìwọ náà rí i, ṣé o sì ti wá mọ̀ báyìí pé mi ò gbèrò láti ṣe ọ́ ní jàǹbá tàbí kí n dìtẹ̀ sí ọ? Mi ò ṣẹ̀ ọ́,+ àmọ́ ńṣe ni ò ń dọdẹ mi kiri láti gba ẹ̀mí* mi.+

  • 2 Sámúẹ́lì 22:21-25
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 Jèhófà san èrè fún mi nítorí òdodo mi;+

      Ó san èrè fún mi nítorí pé ọwọ́ mi mọ́.*+

      22 Nítorí mo ti pa àwọn ọ̀nà Jèhófà mọ́,

      Mi ò hùwà burúkú, kí n wá fi Ọlọ́run mi sílẹ̀.

      23 Gbogbo ìdájọ́ rẹ̀+ wà ní iwájú mi;

      Mi ò ní yà kúrò nínú àwọn òfin rẹ̀.+

      24 Màá jẹ́ aláìlẹ́bi+ níwájú rẹ̀,

      Màá sì pa ara mi mọ́ kúrò nínú ẹ̀ṣẹ̀.+

      25 Kí Jèhófà san èrè fún mi nítorí òdodo mi +

      Àti nítorí mo jẹ́ aláìṣẹ̀ ní iwájú rẹ̀.+

  • Sáàmù 24:3, 4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  3 Ta ló lè gun orí òkè Jèhófà,+

      Ta ló sì lè dúró ní ibi mímọ́ rẹ̀?

       4 Ẹni tí ọwọ́ rẹ̀ mọ́, tí ọkàn rẹ̀ sì mọ́,+

      Ẹni tí kò fi ẹ̀mí Mi* búra èké,

      Tí kò sì búra ẹ̀tàn.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́