Jóṣúà 1:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ìwé Òfin yìí kò gbọ́dọ̀ kúrò ní ẹnu rẹ,+ kí o máa fi ohùn jẹ́ẹ́jẹ́ẹ́ kà á* tọ̀sántòru, kí o lè rí i pé ò ń tẹ̀ lé gbogbo ohun tí wọ́n kọ sínú rẹ̀;+ ìgbà yẹn ni ọ̀nà rẹ máa yọrí sí rere, tí wàá sì máa hùwà ọgbọ́n.+ Sáàmù 119:48 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 48 Màá tẹ́ ọwọ́ mi sókè sí ọ nítorí àwọn àṣẹ rẹ, torí mo nífẹ̀ẹ́ wọn,+Màá sì máa ronú lórí* àwọn ìlànà rẹ.+
8 Ìwé Òfin yìí kò gbọ́dọ̀ kúrò ní ẹnu rẹ,+ kí o máa fi ohùn jẹ́ẹ́jẹ́ẹ́ kà á* tọ̀sántòru, kí o lè rí i pé ò ń tẹ̀ lé gbogbo ohun tí wọ́n kọ sínú rẹ̀;+ ìgbà yẹn ni ọ̀nà rẹ máa yọrí sí rere, tí wàá sì máa hùwà ọgbọ́n.+
48 Màá tẹ́ ọwọ́ mi sókè sí ọ nítorí àwọn àṣẹ rẹ, torí mo nífẹ̀ẹ́ wọn,+Màá sì máa ronú lórí* àwọn ìlànà rẹ.+