Sáàmù 119:81 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 81 Ọkàn mi ń fà sí* ìgbàlà rẹ,+Nítorí ọ̀rọ̀ rẹ ni ìrètí mi.*