-
Sáàmù 9:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Dìde, Jèhófà! Má ṣe jẹ́ kí ẹni kíkú borí.
Jẹ́ kí àwọn orílẹ̀-èdè gba ìdájọ́ níwájú rẹ.+
-
-
Jeremáyà 18:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Ṣùgbọ́n, ìwọ Jèhófà,
O mọ gbogbo ètekéte wọn dáadáa, bí wọ́n ṣe fẹ́ pa mí.+
Má bo àṣìṣe wọn,
Má sì pa ẹ̀ṣẹ̀ wọn rẹ́ kúrò níwájú rẹ.
-