Sáàmù 119:104 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 104 Àwọn àṣẹ rẹ ló mú kí n máa fòye hùwà.+ Ìdí nìyẹn tí mo fi kórìíra gbogbo ọ̀nà èké.+