Ìfihàn 16:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Mo gbọ́ tí áńgẹ́lì tó wà lórí àwọn omi sọ pé: “Ìwọ, Ẹni tó ti wà tipẹ́, tó sì wà báyìí,+ Ẹni ìdúróṣinṣin,+ jẹ́ olódodo, torí o ti ṣe àwọn ìdájọ́ yìí,+ Ìfihàn 16:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Mo sì gbọ́ tí pẹpẹ náà sọ pé: “Jèhófà* Ọlọ́run, Olódùmarè,+ àní òótọ́ àti òdodo ni àwọn ìdájọ́* rẹ.”+
5 Mo gbọ́ tí áńgẹ́lì tó wà lórí àwọn omi sọ pé: “Ìwọ, Ẹni tó ti wà tipẹ́, tó sì wà báyìí,+ Ẹni ìdúróṣinṣin,+ jẹ́ olódodo, torí o ti ṣe àwọn ìdájọ́ yìí,+
7 Mo sì gbọ́ tí pẹpẹ náà sọ pé: “Jèhófà* Ọlọ́run, Olódùmarè,+ àní òótọ́ àti òdodo ni àwọn ìdájọ́* rẹ.”+